Go to full page →

Ìgbé Ayé Wa Gbọ́dọ̀ Kún Ojú Òṣùwọ̀n IIO 211

Gbogbo ogun ọ̀run ni wọ́n ń wo gbogbo olùgbe ayé. Àwọn ańgẹ́lì àti Ọlọ́run ń wo gbogbo àwọn tí wọ́n pe ara wọn ní Onígbàgbọ́ tí wọ́n sì ń gbé ìgbé ayé àdúrà wọ́n lé orí òṣùwọ̀n.-Sings of the Times (Australiasian), June 22, 1903. IIO 211.2