Go to full page →

Ojúkòkòrò IIO 40

Síbẹ̀ àwọn mìíràn kọ̀ láti yípadà.Wọn kò fẹ́ láti rìn ní ọ̀nà ti Ọlọ́run,àti pe nigba ti, kí iṣẹ́ Ọlọ́run ba à le è tẹ̀síwájú ìpè fún ìtọrẹ àánú,ìmọ-tara -ẹni- nìkan mú àwọn mìíràn wowọ́ mọ́ ohun ìní ayé yìí. Àwọn olójú kòkòrò yì í á yà kúrò nínú àwùjọ àwọn onígbàgbọ́.-Testimonies, vol.9,p.126. IIO 40.4