Àwọn ọmọ ìjọ gbọdọ̀ ṣiṣẹ́; wọ́n gbọdọ̀ kọ́ ara a wọn, kí wọn sì là kàkà láti dé ẹ̀kún gíga tí a gbé ka iwájú u wọn. Èyí Ọlọ́run yóò ràn wọ́n lọ́wọ́ láti dé ibẹ̀ tí wọn yóò bá fọwọ́-sowọ́-pọ̀ pẹ̀lú u Rẹ̀.- Testimonies, vol.9, p.140. IIO 62.2
Kí a máṣe jẹ́ kí ọkàn nínú ààyè tí a ní yọ bọ́ nípa mínú wa yẹ nínú ọgbọ́n láti ṣiṣẹ́ fún Ọlọ́run-,- Christ’s Object Lessons, p.334. IIO 62.3