Go to full page →

Pínpín Láìsí Ìyàsọ́tọ̀ IIO 153

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ibi ni a kò ti lè gbọ́ ohùn ìránṣẹ́ Ọlọrun, àwọn ibi tí a ti le lo ìwé àtẹ̀jáde lásan, - àwọn ìwé, àwọn ìwé ìléwọ́ tí ó kún fún òtítọ́ ọ ti Bíbélì tí àwọn ènìyàn nílò. Àwọn ìwé e wa ni a ní láti pín káàkiri. A le è gbin òtítọ́ náà sí ẹ̀bá gbogbo àwọn ọ̀dọ́, nítorí a kò mọ̀ èyí tí yóò ṣe rere, èyí tàbí tọ̀hún. Nínú àwọn ìṣìnà idajọ ọ wa le è rò pé kò mọ́gbọ́n lọ́wọ́ láti fi ìwé fún ẹni tí yóò gba òtítọ́ lọ́wọ́lọ́wọ́. A kò mọ ohun tí ó le è jẹ́ àyọrísí rere nípa fífún ni ní ìwé kékeré tí ó kún fún òtítọ́ ọ ti àsìkò yìí. - Southern Watchman, Jan 5, 1904. IIO 153.3