Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    ORÍ — KEJÌ ÌPÈ SI ÀWỌN Ọ̀DỌ́

    Yíyàn Láti Ọ̀run

    Olúwa ti yan àwọn ọ̀dọ́ láti jẹ́ olùrànlọ́wọ́ ọ rẹ̀.-Testimonies, vol.7,p.64IIO 30.1

    Pẹ̀lú àwọn jagun jagun àwọn òṣìṣẹ́ bí àwọn ọ̀dọ́, tí a kọ́ lọ́nà tòótọ́, tí a fún ní agbára, báwo ni iṣẹ́ ìránṣẹ́ ti Olùgbàlà tí a kàn mọ́ àgbélébùú, tí ó jíǹde àti ìpadàbọ̀ Olùgbàlà yóò ṣe lọ sí gbogbo ayé.-Education, p.271.IIO 30.2

    À ǹ rì ọmọ ogun ti ọ̀dọ́ lónìí tí ó lè ṣe púpọ̀ tí a bá darí i wọn dáadáa tí a sì ń gbà wọ́n níyànjú. A fẹ́ kí àwọn ọmọ wa gba òtítọ́ gbọ́. A fẹ́ kí Ọlọ́run bùkún wọn, a fẹ́ kí wọn kópa nínú ètò tí a gbé kalẹ̀ dáadáa fún ìràn lọ́wọ́ ọ̀dọ́ míràn. Kí a kọ́ wọn dáadáa kí wọn lè jẹ́ aṣojú ti òtítọ́, fún wọn ní ìdí ti ìrètí tí ó wà ní ìkáwọ́ wọn, kí wọn sì bu ọlá fún Ọlọ́run nínú ẹ̀ka kẹ́ka tí wọ́n yẹ lati ṣiṣẹ.-General Conference Bulletin, vol.5,no2,p.24.(Jan.29,30,1893).IIO 30.3

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents