Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Abala Tí ó Gbẹ̀hin Nínú Eré Orí Ìtage.

  Iṣẹ́ ìránṣẹ́ yì í kò tí ì fìgbà kan jáde pẹ̀lú agbára rí bí i ti òde òní. Siwájú àti síwájú sí i ayé ń tẹ ẹ̀tọ́ Ọlọrun mọ́lẹ̀. Ènìyàn ń yigbì nínú rírú òfin. Àwọn olùṣe búburú tí ó jẹ́ olùgbé inú ayé ti fẹ́rẹ̀ kún ojú òṣùwọ̀n ti iṣẹ́ ibi i wọn. Ayé ti fẹ́rẹ̀ dé ibi tí Olọ́run yóò ti gba àwọn olùparun láàyè láti ṣiṣẹ́ lórí èrò o wọn. Fifi òfin ènìyàn rọ́pò o ti Ọlọ́run, nipa gbígbé, nípa àṣẹ ènìyàn lásán, ti ọjọ́ kìn- ín- ní ọ̀sẹ̀ ga dípò ọjọ́ ìsinmi inú u Bíbélì, jẹ́ bí abala tí ó kẹ́hìn nínú eré orí ìtàgé náà. Nígbà tí pàṣípààrọ̀ yì í bá ti kárí ayé, Ọlọ́run yóò fi ara a RẸ̀ hàn. Yóò wá dìde nínú ọlá a RẸ̀ láti mi ayé tìtì. Yóò jáde ní ààyè e RẸ̀ láti fi ìyà jẹ àwọn olùgbé inú ayé fún ìwà ibi, àti pé ayé yóò sì fi ẹ̀jẹ̀ ẹ rẹ̀ hàn, kì yóò sì fi pípa a rẹ̀ ṣe bojú bojú.-Testimonies, vol.7, p.141.IIO 50.2

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents