Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Àpẹẹrẹ Ti Ọ̀run

  Kristi, oníṣègùn ajíhìnrere tí ó tóbi, ni àpẹẹrẹ ẹ wa....Ó ń wo aláìsàn sàn Ó sì ń wàásù ìhìnrere. Nínú iṣẹ́ ìsìn-in RẸ̀, ìwòsàn àti ìwàásù ni a sopọ̀ tímọ́tímọ́. A kò ní láti yà wọ́n sọ́tọ̀ lónì í.- Testimonies, vol.9, pp.170,171.IIO 133.1

  Àwọn ìránṣẹ́ ẹ Kristi ní láti tẹ̀lé àpẹẹrẹ ẹ RẸ̀. Bí Ó ṣe ń lọ láti ibìkan sí èkejì, Ó tu àwọn tí ó ń kerora nínú, Ó sì tún ń wo aláìsàn sàn. Ó sì gbé àwọn òtítọ́ ń lá a nì nípa ìjọba ọ̀run síwájú u wọn. Iṣẹ́ àwọn àtẹ̀lè e RẸ̀ nì yìí. - Christ’s Object Lessons, pp.233, 234.IIO 133.2

  Àwọn tí wọ́n pe ara wọn ní ọmọ Ọlọrun gbọdọ̀ tẹ̀lé àpẹẹrẹ Kristi. Ṣe ìrànwọ́ fún àwọn enìkejì ì rẹ tí wọ́n ṣe aláìní ní ti ara, ìmoore wọn yóò fọ́ àwọn ìdènà, yóò sì jẹ́ kí o le dé àwọn ọkán-an wọn. Gba ọ̀rọ̀ yì í rò tìtara tìtara. - Testimonies, vol.9, p.127.IIO 133.3

  Tí àwọn tí wọ́n jẹ́ oníṣègùn ajíhìnrere pàápàá bá farahàn nínú ẹ̀mí, ọ̀rọ̀ àti ìwà, pé àwọn ń tẹ̀lé Kristi Jesu, àpẹẹrẹ ohun ti ọ̀run ni ti ìgbìyànjú oníṣègùn ajíhìnrere.- Testimonies, vol.7, p.127.IIO 133.4

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents