Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Ṣíṣe Àkójọpọ̀ Àwọn Orúkọ

    Àwọn obìnrin lè ṣiṣẹ́ tí ó níye lorí nípa ṣíṣe àkójọpọ̀ orúkọ àwọn tí ó nífẹ́ ẹ́ sí ìwé àtìgbà- dé- gbà a wa, ní ọ̀nà yii, a le è mú ìmọ́lẹ̀ wá síwájú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọkàn.- Review and Herald, June 10, 1880.IIO 151.3

    A ní ọ̀pọ̀ n ǹkan ń lá tí o lè rọ̀ wá lọ́rùn nípa títan òtítọ́ ká; ṣùgbọn àwọn ènìyàn-an wa kò dìde sí ànfààní tí a fún wọn. Ní ijọ́ kọ̀ọ̀kan wọn kò rí, wọn kò sì mọ ìdí láti lo agbára a wọn láti gba àwọn ọkàn là. Wọn kò náání iṣẹ́ ẹ wọn ní ṣíṣe àkójọpọ̀ orúkọ àwọn tí ó nífẹ̀ ẹ́ sí àwọn ìwé àtìgbà-dé-gbà a wa, pẹ̀lú awọn ìwé àpilẹ̀kọ ọ wa tí ó ní i ṣe pẹ̀lú ètò ìlera a wa, àti láti fi àwọn ìwé e wa àti àwọn ìwé kékeré e wa hàn.- Testimonies, vol.4, p.391IIO 151.4

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents