Go to full page →

Àkọsilẹ Tí ó Lábàwọ́n IIO 45

Ọ̀pọ̀ ló ní ìṣe ti ìwà bí Ọlọ́run, orúkọ wọn sì wà nínú ìwé ìjọ, ṣùgbọ́n wọn ní àbàwọ́n nínú ìwé ìrántí i ti ọ̀run.Áńgẹ́lì olùkọ̀wé pẹ̀lú òdodo ti kọ àwọn ìṣe e wọn. Gbogbo iṣẹ́ ìmọtara ẹni nìkan,gbogbo ọ̀rọ̀ ibi,gbogbo iṣẹ́kíṣẹ́ tí a kò ṣe parí,àti gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ ìkọ̀kọ̀ pẹ̀lú u gbogbo ọgbọ́n àrekérekè àti àgàbàgebè, ni a kọ lọ́kọ̀ọ̀kan láì fi igbá kan bọ̀ kan nínú nínú àwọn ìwé àkọsílẹ̀ lábẹ́ ìṣàkóso àwọn ańgẹ́lì .- Testimonies,vol.2,p.442. IIO 45.2