Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Àkọsilẹ Tí ó Lábàwọ́n

    Ọ̀pọ̀ ló ní ìṣe ti ìwà bí Ọlọ́run, orúkọ wọn sì wà nínú ìwé ìjọ, ṣùgbọ́n wọn ní àbàwọ́n nínú ìwé ìrántí i ti ọ̀run.Áńgẹ́lì olùkọ̀wé pẹ̀lú òdodo ti kọ àwọn ìṣe e wọn. Gbogbo iṣẹ́ ìmọtara ẹni nìkan,gbogbo ọ̀rọ̀ ibi,gbogbo iṣẹ́kíṣẹ́ tí a kò ṣe parí,àti gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ ìkọ̀kọ̀ pẹ̀lú u gbogbo ọgbọ́n àrekérekè àti àgàbàgebè, ni a kọ lọ́kọ̀ọ̀kan láì fi igbá kan bọ̀ kan nínú nínú àwọn ìwé àkọsílẹ̀ lábẹ́ ìṣàkóso àwọn ańgẹ́lì .- Testimonies,vol.2,p.442.IIO 45.2

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents