Go to full page →

Ìrìn-Àjò Àwọn Oníṣègùn Ajíhìnrere IIO 128

Nínú àṣẹ tí Oluwa ti fún mi láti ìgbà dé ìgbà, mo mọ̀ pé àwọn òṣìṣẹ́ tí yóò rin ìrìn-àjò ti oníṣègùn ajíhìnrere láarin àwọn ìlú àti ìletò gbọdọ̀ wà. Àwọn tí ó bá ṣe iṣẹ́ yì í yóò rí ìkórè àwọn ọkàn láti ọ̀dọ̀ àwọn ẹni gíga àti àwọn ẹgbẹ́ tí ó rẹlẹ̀ jù. Ọ̀nà tí a le fi ṣe iṣẹ́ yìí ni mímúra nípa àwọn ìgbìyànjú àwọn olóótọ́ òǹtàwé.- Testimonies, vol.9, p.172. IIO 128.2