Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Ìrìn-Àjò Àwọn Oníṣègùn Ajíhìnrere

    Nínú àṣẹ tí Oluwa ti fún mi láti ìgbà dé ìgbà, mo mọ̀ pé àwọn òṣìṣẹ́ tí yóò rin ìrìn-àjò ti oníṣègùn ajíhìnrere láarin àwọn ìlú àti ìletò gbọdọ̀ wà. Àwọn tí ó bá ṣe iṣẹ́ yì í yóò rí ìkórè àwọn ọkàn láti ọ̀dọ̀ àwọn ẹni gíga àti àwọn ẹgbẹ́ tí ó rẹlẹ̀ jù. Ọ̀nà tí a le fi ṣe iṣẹ́ yìí ni mímúra nípa àwọn ìgbìyànjú àwọn olóótọ́ òǹtàwé.- Testimonies, vol.9, p.172.IIO 128.2

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents