Go to full page →

Ìtànká Erongba Oníṣègùn IIO 137

Oluwa yoo fún àwọn ibi tí a ti ń tọ́jú àwọn aláìsàn tí iṣẹ́ ẹ wọn ti fẹsẹ̀ múlẹ̀ ní ànfààní láti fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú u RẸ̀ nínú ṣíṣe rànwọ́ fún àwọn tí a ṣẹ̀ṣẹ̀ dá sílẹ̀. Gbogbo àwọn ibi kọ̀ọ̀kan tí a ṣẹ̀ṣẹ̀ dá sílẹ̀ ni a ní láti wò bí i olùrànlọ́wọ́ fún ara a wọn nínú ìpolongo iṣẹ́ ìránṣẹ́ ẹ ti ańgẹ́lì kẹ́ta.Ọlọ́run ti fún àwọn ibi tí a ti ń tọ́jú àwọn aláìsàn ní ààyè láti ṣe àgbékalẹ̀ iṣẹ́ tí yóò jẹ́ òkúta ti ìmọ̀ nínú pẹ̀lú ìye tí a gbé kalẹ̀ tí ó ń dàgbà nípa ọwọ́ àìrí. Jẹ́ kí òkúta ìjìnlẹ̀ yìí bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́.- Testimonies, vol.7, p.59. IIO 137.6