Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Ìtànká Erongba Oníṣègùn

    Oluwa yoo fún àwọn ibi tí a ti ń tọ́jú àwọn aláìsàn tí iṣẹ́ ẹ wọn ti fẹsẹ̀ múlẹ̀ ní ànfààní láti fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú u RẸ̀ nínú ṣíṣe rànwọ́ fún àwọn tí a ṣẹ̀ṣẹ̀ dá sílẹ̀. Gbogbo àwọn ibi kọ̀ọ̀kan tí a ṣẹ̀ṣẹ̀ dá sílẹ̀ ni a ní láti wò bí i olùrànlọ́wọ́ fún ara a wọn nínú ìpolongo iṣẹ́ ìránṣẹ́ ẹ ti ańgẹ́lì kẹ́ta.Ọlọ́run ti fún àwọn ibi tí a ti ń tọ́jú àwọn aláìsàn ní ààyè láti ṣe àgbékalẹ̀ iṣẹ́ tí yóò jẹ́ òkúta ti ìmọ̀ nínú pẹ̀lú ìye tí a gbé kalẹ̀ tí ó ń dàgbà nípa ọwọ́ àìrí. Jẹ́ kí òkúta ìjìnlẹ̀ yìí bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́.- Testimonies, vol.7, p.59.IIO 137.6

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents