Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Pàtàkì Ìpọ́njú

  Nígbà ti ìpọnjú tú àwọn aposteli ká, nígbà náà ni wọn tẹ síwájú pẹlú ìtara iṣẹ ìhìnrere nígbà náà ni ojúṣe iṣẹ ìránṣẹ wọn wá hàn sí wọn nígbà tí wọn mọ wípé àkàrà ìyè èyí tí ó wà fún ayé tí ebi ń pa wà lọwọ wọn, ìfẹ Kristi sì wá rò wọn láti màa fún àwọn tí wọn ṣe aláìní ní àkàrà ìyè yìí.-The Acts of the Apostles, p. 106.IIO 159.2

  Ọlọrun mọ wipe dídán òtítọ wò jẹ ohun tí a óò mú wá sí gbangba tí yóò sì jẹ ohun tí a a óò yẹwò àti ti á o sì jíròrò lé lórí nípasẹ ojú ẹtánú tí a óò fi ṣe àyẹwò rẹ. Ọkàn ìbínú ni lati gbe àwọn eniyan wo ki gbogbo ijakadi, ẹtanu, ọrọ eke le jẹ ọnà ti Ọlọrun yóò gbà ta gbogbo ọkàn tí o ńtòògbé jí lati ṣe ìwádìí àwọn ohun tí ó le ta ọkàn wọn jí.-Testimonies, Vol. 5, p. 453.IIO 159.3

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents