Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Òdiwọ̀n- ọn Ti Ọlọ́run

    Òṣùwọ̀n ti ìwà a wa ni ó ń lọ lọ́wọ́lọ́wọ́. Àwọn ańgẹ́lì ọ̀run ń díyelé iye tí ìwà à rẹ tó, wọ́n sì wádì í àwọn àìní ì rẹ, wọ́n sì ń gbé ẹjọ́ ọ̀ rẹ sí ọ̀dọ̀ Ọlọrun.- Review and Herald,April 2,1889.IIO 86.1

    A yóò dúró ní ẹnìkọ̀ọ̀kan fún ṣíṣe kín-kin-ní ju ohun tí a lágbára láti ṣe.Oluwa ń wọn ìṣe dééédé ànfààní kánfààní fún iṣẹ́ ìsìn. Àwọn agbára tí a kò lò ni a ti gbé gbe sórí ìṣirò bí àwọn tí a túnṣe. Fún gbogbo ohun tí a lè dà nípa lílo àwọn tálẹ́ńtì lọ́nà tó dára,Ọlọrun yóò bí wá léèrè. A yóò dá wa lẹ́jọ́ gẹ́gẹ́ bí ohun tí ó yẹ kí a ṣe, ṣùgbọ́n tí a kò ṣe láṣepé nítorí pé a kò lo agbára wa láti yin Ọlọrun lógo. Bí a kò tilẹ̀ sọ ẹ̀mí i wa nù, a máa mọ̀ ní ayérayé àyọrísí àwọn tálẹ́ńtì i wa tí a kò lò. Nítorí gbogbo ìmọ̀ àti agbára tí ó yẹ kí a jèrè tí a kò sì jèrè, ni yóò jẹ́ òfò ayérayé.- Christ’s Object Lessons, p.303.IIO 86.2

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents