Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Ẹ̀KỌ́ KEJÌLÉLÓGÚN ÌPÀDÉ ÀDÚRÀ ÀTI IṢẸ́ ÌHÌNRERE

  Àṣírí Àdúrà Tí Ó Jẹ́ Ìtẹ́wọ̀gbà

  Ìdàgbásókè tàbí ìfàsẹ́hìn ìjọba Ọlọ́run dá lórí jíjẹ̀ olóòtítọ́ tàbí àìjẹ́ olóòtítọ́ ènìyàn tí wọ́n jẹ́ ohun èlò Ọlọ́run. Ìdènà bá iṣẹ́ yìí nítorí ènìyàn kọ̀ láti fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú Ọlọ́run. Ènìyàn lè gbàdúrà wí pé, “Kí Ìjọba Rẹ̀ Dé. Ìfẹ́ Tirẹ̀ ni kí a ṣe ní ayé, bí wọ́n ti ń ṣe lọ́run” , ṣùgbọ́n tí wọ́n bá kùnà láti fi àdúrà yìí ṣe ìwà hù, àdúrà wọn yóò jásí asán.IIO 211.1

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents