Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Ìdánilójú Wà Fún Èsì Tí ó Dára.

    Tí àwon omo ìjo tí kìí se àlúfà bá dìde láti se isé èyí tí wón leè se, tí wón ńtèsíwájú ní dídi àmùrè won pèlú bí agbára wón tí mo tí olúkúlùkù sì ńtiraka láti jèrè okàn fún Jésù, a ó rí òpòlopò tí wón yóò bà kúrò nínú egbé Sátánì wá sí ibi àsíá Kristi. Tí àwon ènìyàn wa bá le tèlé ìmòràn yìí, dájúdájú a ó rí ìgbàlà Olórun. A ó jèrè okàn àwon elésè bẹ́ẹ̀ sì ni òpòlopò naa ó sí yán kún ìjo.-Testimonies, Vol 8, p. 246.IIO 184.1

    Àwon omo ìjo wà gbodo ní ìfé tó jinlè sí isé ìhìnrere nítòsí ní ó tàbí lókèèrè. Ìbùkún lópòlópò ní ó sì jẹ́ ti won bá sa ipá won láti fi ara won jìn láti fi ìdí òtító múlè ní àwon agbègbè tuntun. Owó tí wọn bá ná lórí isé yìí yóò mú èrè tó pọ̀ wá. Àwon okàn tuntun tí a jèrè pèlú ayò ní okàn won nítórí ìmólè ọ̀rọ̀ Rè tí wón ńgbà yóò fi tayòtayò fi sílè láti leè mú ìmólè òtító tọ àwon elòmíràn lọ.-Testimonies, Vol. 9, p. 49.IIO 184.2

    Ní àwon agbègbè tí won bá tí dojúko ìsòro tí àwon ènìyàn bá kò jálè láti lọ, àwon omo ìjo gbódo gbé ìgbése tó lágbára èyí tí yóò mu ìyípadà wá nípa ìfira-eni rúbò. Àwon òsìsé onírèlè yìí yóò se àseyorí púpò nítorí sùúrù wọn, èmí-ìfaradà won àti ìgbékèlé won nínú Olórun, èyí tí Ó ń sàánú fún won. Àseyorí isé àwon wònyí ni a kò ní leè mọ̀ láyé.IIO 184.3

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents