Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Máṣe Àníyàn

  N ǹkan yóò bàjé nítori àwon òsìsé tí a kò yà sí mímó. Ó lè sunkún nítorí àbáyorí èyí, sùgbón má mikàn. Olórun mo ìbèrè àti òpin isé Rè. Ohun tí ó béèrè kìkì àwon òsìsé Òun kí ó tó o wá pèlú àse Rè, kí won ó sì tèlé ìlànà Rè. Ohun gbogbo — ilé-ìjósìn wa, isé ìsìn, ìsinmi wa, ilé-ìwé wa àti ilé-isé ẹ wa gbodò gbé èmí iyì Rè wò. Kíni ìdí tí o fi ń mikàn? Ìrètí láti rí ilé-ìjósìn gégé bí iná tí ó ń tàn àti èmí ààyè bí Olórun se pe nílo wa láti se èyí pèlú ìgbàgbó nínú Olórun.-Review and Herald, Nov. 14, 1893.IIO 243.1

  Kó láti ní ìfàyàbalè, kí o sì fi pípa èmí re mó sówó Olórun gégé bí Elédàá Olóòótó. Yóò pa ohun tí a fi sí ìkáwó Rè mó. Kò fé kí a fi ekún àti asò wá sí ibi pepe Rè. O ní òpòlopò ohun láti yin Olórun fún, tí o bá rí èmí tí ó sonù yípadà. Sùgbón isé rere yóò tèsíwájú tí o bá lè tèsíwájú láì gbìyànjú láti yí ohun gbogbo sí ìmò tìre nìkan. Jé kí àlàáfíà Olórun joba nínú re, kí o sì má dúpé. Jé kí Olorun ní ibùgbé láti sisé, máse dí ònà Rè. Ó lè, yóò sisé tí a bá lè gbà á láàyè.-Testimonies, Vol. 9, p. 136.IIO 243.2

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents