Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    ORI — KẸ́RIN ÀWỌN IPÒ TÍ AYÉ WÀ TÍ Ó Ń DOJÚKỌ ÒṢÌṢẸ́ ONÍGBÀGBỌ́

    Eré Orí Ìtàgé e Ti Ayé

    Ilé ayé jẹ́ orí ìtàgé, àwọn òṣèré jẹ́,àwọn tí ó ń gbé inú u rẹ̀, ti o ǹ gbàradì láti kópa tó yẹ kí wọn kò nínú eré ń lá tó gbèhìn. Pẹ̀lú àwọn ọgọọrọ eniyan,kò sí ìrẹ́pọ̀,àfi tí àwọn ènìyàn bá kóra jọ pọ̀ láti mú èrò ìmọtara ẹni nìkan ṣẹ. Ọlọ́run fọwọ́ lẹ́rán Ó ń wò wọ́n. Ìpinnu u RẸ̀ sí àwọn ọlọ̀tẹ̀ olùgbé ibẹ̀ yóò wá sí ìmúsẹ.A kò tí ì fi ilé ayé sí ọwọ́ ènìyàn, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Ọlọ́run ń gba àwọn n ǹkan rúdurùdu àti ìdàrú dàpọ̀ láàyè láti borí fún ìgbà díẹ̀. Agbára kan ń ṣiṣẹ́ labẹ́nú láti mú abala tí ó kẹ́hìn nínú eré orí ìtàgé náà, - Èṣù ń wá bí i Krístì, ó sì ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú gbogbo ẹ̀tàn ti àì ṣòdodo nínú àwọn tí wọ́n ti so ara wọn pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òkùnkùn. Gbogbo àwọn tí wọ́n sì ǹ tẹ̀ sí ìwà ìdìmọ́ ọ rẹ̀ ń ṣiṣẹ́ fún ìlànà ti ọ̀tá. Igbesẹ naa yoo lẹyin. - Testimonies, vol.8, pp.27, 28IIO 50.1

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents