Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Ìṣọkan Ìpọ́njú Onípelemẹ́ta

  Nípasẹ àṣiṣe ńlá méji, èrò wípé ọkàn ènìyàn kìí kú àti yíya ọjọ kìn-ín-ní ọsẹ si mimọ ni eṣu yóò ti mu ki gbogbo awọn ènìyàn ó wa labẹ itanjẹ rẹ. Nígbà ti àkókó ń fi ìpìlẹ ẹmi òkùnkùn múlẹ, èkejì ń fi ìdè ìkáànú pẹlú awọn Róòmù hàn. Awọn ijọ ti o yapa ti ó wà ni orílẹ èdè Amẹríkà ni wọn kọkọ tẹwọgbà ẹmi òkùnkùn tíí ṣe ti abókùúsọrọ, wọn óò sì na ọwọ wọn láti fọwọsowọpọ pẹlú agbara Róòmu ati labẹ àkóso awọn agbara iṣọkan mẹta yìí ni orilẹ èdè yìí yóò fi tẹlé awọn ìgbesẹ Róòmu nipa titẹ ẹtọ ọkàn ènìyàn mọlẹ.-The Great Controversy, p. 588.IIO 160.1

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents