Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Pẹ̀lú Ojú Tí ó Ti Fọ́

    Ọpọlọpọ àwọn tí ó kópa láti fi ìsinmi ọjọ kìn-ín-ní ọsẹ múlẹ ṣugbọn ni wọn foju si àyọrísí ìgbésẹ wọnyìí. Wọn kò sì mọ, ń ṣe ni wọn ńgbógun ti òmìnira ẹsìn. Bẹẹ sì ni ọpọlọpọ ni òye ọjọ ìsinmi, ọjọ kèéje ti ìnu Bíbélì kò ye àti ìpìlẹ èké èyí tí ọjọ kìn-ín-ní ọsẹ dúró lé.-Testimonies, Vol. 5, p. 711.IIO 161.3

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents