Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Àpẹẹrẹ Rere

    Àpóstélì (Pọ́ọ̀lù) rò pé lọ títí ni òun wà fún ìṣàkóso ti ìlera ti ẹ̀mi àwọn tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ yípadà ní abẹ́ iṣẹ́ ẹ rẹ̀. Ohun tí ó fẹ́ fún wọn ni pé kí wọn lè dàgbà nínú ìmọ̀ ọ ti Ọlọ́run òtítọ́ nìkan, àti Jésù Krístì ẹni tí Ó rán. Báyì í nínú iṣẹ́ ìránṣẹ́ ẹ rẹ̀ yóò bá àwọn ẹgbẹ́ ké kè ké lọ́kùnrin àti lóbìnrin pàdé tí wọ́n fẹ́ Jésù tí wọ́n sì tẹríba nínú àdúrà, tí wọ́n sì ń bèrè lọ́wọ́ Ọlọ́run láti kọ́ wọn bí wọ́n ṣe lè dúró nínú ìdàpọ̀ pẹ̀lú u Rẹ̀. Ọ̀pọ̀ ìgbà ni ó ń gbà wọ́n nímọ̀ràn bí fún ìlànà tí ó dára nípa fí fifún àwọn mìràn ìmọ́lẹ̀ ti òtítọ́ ìhìnrere. Àti ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà, ó ń bẹ Ọlọ́run láti pa wọ́n mọ́ lọ́wọ́ ewu, kí ó sì rán wọ́n lọ́wọ́ láti lè jẹ́ olùfọkànsìn ajíhìnrere tí ó sì jẹ́ akíkanjú.- The Acts of The Apostles, p.262.IIO 71.1

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents