Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Ìkẹ́kọ̀ọ́ Pàtàkì

    Àwọn ìgbìyànjú tí ó tóbi ni a gbọdọ̀ gbé síwájú láti kọ́ àwọn ènìyàn nínú àwọn ìpìlẹ̀ ti àtúnṣe ètò ìlera. Ilé-ìwe tí a ti ń ṣe oúnjẹ gbọdọ̀ wà ní dídá sílẹ̀ àti láti ojúlé —dé- ojúlé ni a gbọdọ̀ ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún nípa ọ̀nà tí a fi le ṣe oúnjẹ dáradára. Níbikíbi tí a bá ti ń sọ nípa òtítọ, a gbọdọ̀ kọ́ àwọn ènìyàn lọ́nà tí wọn fi le ṣe oúnjẹ lọ́nà tí ó rọrùn, síbẹ̀ ní ọ̀nà tí yóò fi wuni láti jẹ ẹ́. A ní láti fihàn wọ́n pé oúnjẹ tí ó ń ṣara lóore ni a le sè láì si ẹran.- Testimonies,vol.9, p.161.IIO 59.4

    Ní gbogbo ibi tí ìjọ bá wà, a gbọdọ̀ fún wọn ní ẹ̀kọ́ nípa kíkíyèsí àti ṣe ìtọ́jú oúnjẹ tí ó rọrùn, tí ó dára fún àwọn tí wọ́n fẹ́ láti gbé ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú àgbékalẹ̀ tí ètò ìlera.Àti pẹ̀lú kí àwọn ọmọ ìjọ fi kọ́ àwọn ènìyàn tí ó wà ládúgbò o wọn ìmọ́lẹ̀ tí wọ́n ti gbà lórí ẹ̀kọ́ yìí.-Gospel Workers, p.362.IIO 60.1

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents