Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Iṣẹ́ Ìránṣẹ́ ẹ Ti Ilé Àti Iṣẹ́ Ìránṣẹ́ ẹ Ti Òkèèrè

  Isé ìránsé tí ilé tàbí tí ìtòsí wá yóò ní ìtèsíwájú tí ó tayo nígbàtí a bá ní èmí ìséra ení tàbí tí ìfi árà ení jìn fún àseyorí isé ìránsé tí òkèèrè nítorípé ìdàgbàsókè tàbí àseyorí isé ìránsé òkèèrè ní ó máa ń jẹ́ kí isé ìhìnrere tí ilè ó fi esẹ̀ múlè. Ìgbà tí a bá fi gbogbo okàn wá sisé láti se àtìléhìn fún isé Olúwa nígbànáà ní okàn wá gba ìfọwótọ́ láti òdò Eni tí ó jé orísun gbogbo agbára.- Testimonies, Vol. 6, p. 27.IIO 170.4

  Onísòwò ìlú Améríkà kàn tí ó jé Onígbàgbó so wípé gbogbo ojó ní òun fi má sisẹ́ fún Kristi. Ó so wípé, “Nínú gbogbo idókòwò mí pèlú àwon oníbàrá mi ní mo máa ń gbìyànjú láti jé asojú fún Olùgbàlà mi. Gbogbo ìgbà tí mo bá tí ní àǹfaàní ní mo máa ń pe àwon okàn wá sí òdò Rè. Gbogbo ìgbà ní mo máa ń sisé fún Kristi. Nígbàtí mo bá tilè sùn lóru béèní mo ní okùnrìn kan tí ó ńsisé ìjèrè okàn yìí fún ní China”. Nínú àlàyé rè, ó so wípé: “Láti kékeré ní mo tí pinnu láti jé òsìsé fún Olórun ní ilè àwon kèfèrí. Sùgbón nígbàtí bàbá mi kú, mo ní láti téwógba okòwò rè láti leè pèsè fún ìdílé wá. Nísisìyí, kàkà kí n má kúkú jé ajíhìnrere, mo ń se àtíléhìn fún àwon ajíhìnrere. Ní ìlú China, mo ní àwon ajíhìnrere níbè. Nítorínáà, nígbàtí mo bá ń sùn mo sì ńsisé ajíhìnrere nípasè asojú mi”.IIO 170.5

  Sé kò sí omo ìjo Onírètí èyí tí ó lè se bẹ́ẹ̀ ní? Kàkà tí a ba fi dá àwon òsìsé wọ̀nyí dúró sínú ìjo tí ó tí mo òtító, ẹ jé kí àwon omo ìjo so fún won. “E jáde lo se àwárí àwon okàn tí ń sègbé, ẹ jé kí àwa tó kù ó máa darí isé ìsin lo. À ò se àmójútó ohun gbogbo tí ó ye kí á se àti nípa wíwà nínú Kristi a ó sì máa dàgbá nínú èmí. A ó máa sisé fún àwon okàn tí ó wà nítòsí wa, a ó sì máa fi àdúrà àti àwon èbùn wa ránsé sí àwon òsìsé tí wón se aláìní tàbí ní àwon agbègbè tí ó dàbí ení pé àwon ènìyàn tí kọ̀ sílè.-“Testimonies, Vol. 6, pp. 29, 30.IIO 171.1

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents