Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Kíkú Nínú Ìrékọjá Àti Ẹ̀ṣẹ

  Lónì í,ọ̀pọ̀lọpọ̀ nínú ìjọ ni wọ́n ti kú sínú irékọjá àti ẹ̀ṣẹ̀.Wọ́n ń lọ, wọ́n ń bọ̀ bí i ìkẹ̀kùn tí kò ní ìdádúró. Fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún wọ́n fi ẹmi itẹra ẹni lọ́rùn fara balẹ̀ gbọ́ ọ̀rọ̀ òtítọ́ tí ó lè tanijí, ṣùgbọ́n wọn kò fi ṣe ìwà hù. Fún ìdí èyí, wọ́n kéré àti pé òye wọn kéré sí ti òtítọ́ ti iyebíye....Nígbà tí wọ́n ń ṣe ìjẹ́wọ́, wọ́n ṣe agbára ti ìwà bí Ọlọ́run.Tí wọ́n bá sì tún wà ní irú ipò báyì í, Ọlọ́run á kọ̀ wọ́n sílẹ̀.Wọn kò yẹ láti jẹ́ ara ìdílé Ọlọ́run.-Testimonies,vol.6,pp.426.427.IIO 44.3

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents