Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Púpọ̀ Ni À Ń bèèrè Lọ́wọ́ ọ Wa Ju Ti Àwọn Baba a Wa

  Àwọn ìmọ́lẹ̀ ń lá tí ó tóbi jù ni ó tàn sórí i wa ju èyi tí ó tàn sórí àwọn baba a wa. A kò lè jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà tàbí bu ọlá fún wa níti Ọlọ́run nínú ṣíṣe ìsìn kan náà, tàbí ṣiṣẹ́ irú iṣẹ́ kan náà tí àwọn baba a wa ti ṣe. Kí a ba a lè jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà àti ẹni ìbùkún níti Ọlọ́run bí wọ́n ṣe wà, a nì láti ṣe àfarawé ìṣòtítọ́ àti ìtara a wọn, - kí a ṣe àtúnṣe àwọn ìmọ́lẹ̀ ẹ wa bí àwọn náà ṣe ṣ'àtúnṣe ti wọn.Kí a sì ṣe bí wọn ì bá ṣe ṣe tí wọ́n bá ń gbé ní àsìkò o tiwa. A gbọdọ̀ rìn nínú ìmọ́lẹ̀ èyí tí ó ń tàn sórí i wa; bíbẹ́ẹ̀ kọ́ ìmọ́lẹ̀ náà yóò di òkùnkùn. - Testimonies, vol.1, p.262.IIO 88.2

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents