Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Àwọn Ohun Tí ó Ṣe Pàtàkì Fún Àṣeyọrí

    Kí á tó leè mú ìmò òtító àkokò yìí tọ àwon elòmíràn lo, ẹ jé kí á kókó ya ara wa sí mímó fún enití a fé gbé orúko rè ga, kí á sì gba àdúrà gidigidi fún àwon tí a fé bẹ̀wò, ní pà ìgbàgbó tó wa láàyè kí a sì mú wọn wá léjo kòòkan síwájú Olúwa. Olúwa mo èrò òkan ènìyàn gbogbo, Ó mo bí ó se lè mú wá àti gégébí Emí Mímó tí leè tẹrí okàn tó le ba, Ó mo bí Ó se lè fi ìfé kún okàn wa! Ó mo bí Ó se lè fún wá ní oore òfé Èmi Mímó àti bí Ó se lè mú wa ye láti lè sisé fún ìgbàlà àwon okàn.-MS, “Consecrated Efforts to Reach Unbelievers, “June 5, 1914.IIO 169.2

    Isé Olúwa ìbá tí tèsíwájú ju báyì lo tí ó bá jé wípé a fi ogbón bá àwon ènìyàn sòrò tí a sì fún won ní àǹfaàní láti se ohun tí ó ye fún ìdàgbàsókè isé yìí. Tí àwa gégébí ìránsé Rè bá tèlé ìlànà tí ó tó tí ó sì ye.-Southern Watchman, Mar. 15, 1904.IIO 170.1

    Ìba jẹ́ wípé gbogbo àwon òsìsé Olórun bá mò bí Olórun tí gbékèlé òdodo àti èrò tó mógbòn wá, àseyorí ńlá ní yóò jẹ́ ìpín làálàá wọn.IIO 170.2

    Nípa ìfàséhìn àti ìtìju, a máa ń bàkù láti rí ohun tí ó tò gbà. Olórun yóò sisé fún wá nígbàtí a bá tí setàn láti se ohun tí ó ye.-Southern Watchman, Mar. 15, 1904.IIO 170.3

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents