Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Òfin Pípamọ́ Aṣọ ìlékè fún Ẹ̀ṣẹ̀

  Ẹ̀wu kan náà sì ń jẹ jáde lónì í láarin àwọn ènìyàn tí wọ́n ń dúró gẹ́gẹ́ bí ibi ìṣúra fún òfin Ọlọ́run fún. Wọ́n múra láti fi ara wọn ṣ’ẹlẹ́yà pé bíbu ìyin fún-Un nínú bí wọ́n ṣe mú àwọn òfin yóò gbà wọ́n kúrò nínú ìdájọ́ ọ̀run. Wọ́n kọ̀ ibawi fun ibi, wọ́n ń ka ẹ̀sùn sí ìránṣẹ́ Ọlọ́run l’ọ́rùn fuń àìgba ẹ̀ṣẹ̀ láàyè nínú àgọ́.Ọlọrun ti o korira ẹṣẹ n pe awọn tí wọ́n ṣe ijẹ́wọ́ pipa òfin RẸ mọ́ láti kúrò nínú iṣẹ́ ibi.Kikọ́ láti ronú pìwàdà àti ìgbọràn sí ọ̀rọ̀ ọ RẸ̀ yóò mú àyọrísí tí ó léwu sórí àwọn ọmọ Ọlọ́run bí ó ṣe rí fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì àtijọ́ tí wọn ṣẹ irú ẹ̀ṣẹ̀ náà. Gbèdéke wà tayọ èyí tí kò fi ní fi ìdájọ́ rẹ̀ jáfara.-Testimonies,vol.4, pp.166,167.IIO 44.2

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents