Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Ki i ṣe Awọn Olupese ṣugbọn Awọn

    Ti Wọn n lo Ohun Ti a Npese Àwọn tí wọ́n pe ara wọn ní àtẹ̀lé e Krístì wà nínú ìdánwò níwájú Ọlọ́run àgbáyé;Ṣùgbọ́n, ìrẹ̀wẹ̀sì ìtara a wọn àti àìlera akitiyan wọn nínú iṣẹ́ ìsìn fiwọ́n hàn bì alàì sòdodo. Tí ohun tí wọ́n ń ṣe bá jẹ́ ohun tí ó dára jùlọ ní ìkáwọ́ ọ wọn, a kì bá tí dá wọn lẹ́bi; ṣùgbọ́n tí ó bá jẹ́ pé wọ́n fi ọkàn-an wọn jì fún iṣẹ́ náà ni wọn ì bá ṣe ju bẹ́ẹ̀ lọ. Wọ́n mọ̀, ayé sì mọ̀ pé wọ́n ti sọ ipò ẹ̀mí ìṣéra ẹni àti gbígbé àgbélébùú.Níbẹ̀ ọpọ ni wọ́n tako àwọn tí wọ́n má a rí orúkọ wọn nínú ìwé e ti ọ̀run, kì í ṣe olùpese, bíkòṣe àwọn tí wọ́n ń lo ohun tí a pèsè. Ninu awọn ọ̀pọ̀ tí wọ́n ń jẹ́ orúkọ mọ́ Kristi lara,a tàbùkù ògo o RẸ̀, ìbòjú sì bo ẹwà RẸ̀, ọ̀wọ̀ ọ RẸ̀ si farasin . Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni orúkọ wọn wà nínú ìwé ìjọ, ṣùgbọ́n tí kò sí lábẹ́ ìṣàkóso Ọlọ́run. Wọn kò gbọ́ràn sí àṣẹ RẸ̀ tàbí kí wọn ṣe iṣẹ́ ẹ RẸ̀. Fún ìdí èyí, wọ́n wà ní abẹ́ ìṣàkóso ọ̀tá. Kò sí ohun rere kan tí wọ́n ń ṣe, fún ìdí èyí, ìpalára nípasẹ̀ ẹ wọn kò lódiwọ̀n Nítorí pé ipa wọn kò mú adùn ìyé ba ayé, ó jẹ́ adùn tí ikú dé ikú.- Christ Object Lessons, pp.303,304IIO 44.1

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents