Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Òrò Òlàjú

    Òlàjú tòótó àti agbára tí ó wà nínú òrò níí se ní gbogbo ònà pèlú isé Onígbàgbó. Ó ye kí a kó bí a sé ń sòrò ní ònà tí ó wuyì, nípa lílo èdè ní ònà tí rere èyí tí ó dára pèlú òyàyà tí ó sì tó.-Christ’s Object Lesson, p. 336.IIO 223.4

    Gbogbo àwon oníwàásù àti olùkó ni ó ye kí won mò wípé isé ìránsé ti ayérayé ni àwon ń fún ènìyàn. Òtító òrò tí a so ni yóò sì dá won lẹ́ọ́ú ní òjó ìdájó. Bí a se ń gbé òrò kalè níwájú àwon ènìyàn ni yóò jé kí ó jé ìtéwógbà tàbí ìkòsílè níwájú won. Nítorí náà e jé kí òrò enu wa ó dùn mó won létí kí ó sì pàrowà fún okàn won tóbéè tí yóò fi ní ìtumò ní okàn won. Ní díèdíè pèlú ònà tí ó yàtò tí ó sì lówò pèlú ìtara kíkan-kíkan èyí tí yóò lè fa pàtàkì isé náà yo ni a gbé òrò wa kalè níwájú won.-Christ’s Object Lesson, p. 336.IIO 224.1

    Bí a se ń gbìyànjú láti fa àwon ènìyàn tó kù tí ó wà nínú agbo ìfé Rè, e jé kí òrò enu wa tí ó mó gaara, isé ìsìn tí kò ní ìmò-ti-ara-eni nìkan àti ayò ìwà rere wa jérìí sí agbára oore-òfé Rè.-The Ministry of Healing, p. 156.IIO 224.2

    Gbogbo Onígbàgbó ni a pè láti jé kí gbogbo eniyan kó mò nípa òrò Kristi tí kò se é wádìí, nítorí náà e jé kí a ṣóra púpò nípa òrò enu. E jé kí a gbé òrò Olórun kalè ní ònà tí yóò fi ní ìtumò létí àwon olùgbó. Kìí se àgbékalè Olorun nipé kí àwon tí ó ń s o òrò Rè kó jé àjèjì lódò àwon ènìyàn.Kìí ṣe ìfé ẹ Rẹ̀ kí àwon ènìyàn tí ó ń so òrò Rè di yepere.-Christs’ Object Lessons, p. 336.IIO 224.3

    E jé kí a kó pèlú sùúrù, inú rere, pèlépèlé àti ònà tí ó ran ni lówó. nígbà tí a bá gbé ìgbé ayé Kristeni tòótó nítorí wọ́n mò pé Kristi tí ó jé Olùbádámòràn won kò fé òrò tó le tàbí òrò búburú. Òrò ọ wọn yóò jé mímó, agbára òrò tí a fifún won jé èbùn pàtàkì tí a yá wọn láti ṣe iṣé tí ó ga tí ó sì jẹ́ mímọ́.-Gospel Worker, p. 97.IIO 224.4

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents