Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Ábráhámù Àpeere Kan Tí Ó Ye

    Kò sí ìdánwò ìmólè Kankan tí a mú to Abrahamu wá béèni kò sí ètùtù kàn tí a bèèrè lọ́wọ́ rè. Sùgbón, a rií wípé ìrépò ńlá wà láarín rè àti orílè-èdè rè, àwon ènìyàn rè àti ilé rè. Sùgbón, kò jáfara láti gbọ́ ìpè. Kò ní ìbéèrè Kankan láti béèrè nípa ilè ìlérí náà — bóyá ilè olórà ní o tàbí agbègbè tó báni lára mu, tàbí ilè tí a tí lè ní ọ̀rọ̀. Nítori tí Olórun ti sòò, ìránsé ré gbódò gbọ́ àti wípé ibi tí ó le fún ní láyò jú lórí ilè alààyè ní ibi tí Olórun fé kí ó wà.IIO 181.2

    A sì ńdán òpò ènìyàn wò lónì bí Abrahamu. Won kò gbó ohùn Olórun tààrà kí Ó bá won sòrò láti òrun sùgbón Ó pè wón nípasè ìkóni òrò Rè. Ó lee mú kí wọn ó fi isé won èyí tí ó ń fún wọn ní ọrọ̀ àti olá, tàbí kí wọn ó fi agbègbè tí ó fanimóra sílè tàbí kí wón ó lọ kúrò ní òdò àwon ìbátan kí won sì wá wo ònà tí ó fi ara jo ìséra-eni, ìpónjú àti ìfara eni rúbọ. Olórun ní isé pàtàkì fún won láti se sùgbón ìgbé ayé jèléńké tàbí ìpa òré tàbí ìbátan lórí won lè mú àwon ohun tí ó lè mú ìjákulè bá isé náà wá. Ó pè wọ́n jáde kúrò lódò ipa tàbí ìrànlówó àwon ènìyàn, Ó sì tọ́ wọn láti mo ìdí fún ìrànlówó Rẹ̀ àti láti gbékèlé Òun nìkan soso kí Ó bà lè fi ara Rẹ̀ hàn fún wọn.IIO 181.3

    Tani ẹni tí ó setán láti gba ìpè ìpèsè yìí kí ó sì wá kọ àwon èròǹgbà okàn rè àti àwon ebí àti àwon egbé ré? Tani yóò gbé isé tuntun kí ó sí wo ibi tí a kò wò rí, tí ó sì ń se isé Olórun pèlú okàn ìfé àti èmí ìdúró sinsin, nítorí Kristi tí ó sì ń ka àwon oró ayé sí òfo? Eni tí ó ba se eléyìí dájúdájú irú eni bẹ́ẹ̀ ní ìgbàgbó Abrahamu, yóò sì se alábàápín pèlú rè ohun tí, “Ó jé ògo ayérayé tí ó tayo ohun gbogbo”, èyí tí a kó leè fi, “àwon ìjìyà tí àkokò yìí wé.-“Patriarch and Prophetss, pp. 126, 127.IIO 181.4

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents