Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  ÈKÓ KẸRÌNLÉLÓGÚN AYỌ ÀMÚYẸ FÚN ÀṢEYORÍ IṢÉ ÌSÌN ONÍGBÀGBỌ́

  Agbára Láti Sisé

  Àìbìkíà àti àìlágbára fún isé jé ohun àìbòwò fún Olorun. Nígbàtí a bá mò wípé à ń sisé fún Olorun, a yóò ní ìtara púpò sí ohun tí íse ti èmí ju ti télè lo. Níní ìmò yìí ni yóò jé kí a tají, kí a ní ìtara àti àkíyèsí pèlú agbára ìfaradà láti se gbogbo isé.-Testimonies, Vol. 9, p. 150.IIO 223.1

  Àkókò yìí kò gba fífi òle sisé bíkòse kí a fi agbára sisé pèlú ìyara-eni-sótò tó jinlè. Háà, òrò yìí wò mí lára tóbéè gé tí mo fi kígbe sí Olórun wípé “Dìde kí O sì rán àwon òsìsé tí ó mo ojúse won, àwon tí wón ti kan ìwà èsè àti ìbòrìsà mó àgbélébùú.-” Testimonies, Vol. 9, p. 27.IIO 223.2

  Isé tí a gbé lé àwon omo èhìn lówó jé isé tí wón gbodò fi gbogbo agbára se nítorí èsù ń lo gbogbo agbára rè láti gbógun tì wón.-The Act of Apostle, p. 31.IIO 223.3

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents