Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Ṣíṣe Pẹ̀lú Àwọn Àgbékalẹ̀ Tí a Le è Se Àfiwé e Rẹ̀

    Pọ́ọ̀lù jẹ́ ẹnìkan tí ó ní ẹ̀bùn ọ̀rọ̀ sísọ. Kí ó tó di pé ó ní ìyípadà ọkàn, ó má ń wá ọ̀nà láti mú inú àwọn olùgbọ́ ọ rẹ̀ dùn nípa àwọn àgbọ́ gbárímú ẹwà èdè Sùgbọ́n ní báyìí, ó gbé e tì sẹ́gbẹ̀ ẹ́ kan. Dípo tí yóò ga ara a rẹ̀ nípa fífi ewì ṣàpèjúwe àti afijọ to lẹwa, èyí tí ó lè wúni lórí tí yóò sì ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìwòye e wọn, ṣùgbọ́n tí kò ní í ṣe pẹ̀lú ìrírí i wọn ojoojúmọ́, Pọ́ọ̀lù wá ọ̀nà láti lo èdè tí ó rọrùn láti sọ ojú abẹ níkò ó níti òtítọ́ tí ó jẹ́ kò-se-é-má-nìí. Fífi ọ̀rọ̀ àsọdùn ṣe àfiwé òtítọ́ le è mú ni yọ̀ sódì; Ṣùgbọ́n ní ọ̀pọ̀ ìgbà, òtítọ́ tí a gbé kalẹ̀ ní ọ̀nà yìí kò ní fún ni lókun tí ó yẹ tí yóò sì dáàbò bo onígbàgbọ́ fún àwọn ogun ti ayé. Àwọn ohun tí a nílò lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, àwọn ìdánwò o ti àsìkò yìí, tí àwọn ọkàn tí ó ń jìjàkadí,-gbogbo eléyìí ni a gbọdọ̀ bá pàdé pẹ̀lú ẹ̀kọ́ tí ó ṣe pàtàkì tí ó sì múná dóko nínú àwọn àgbékalẹ̀ ti onígbàgbọ́. - The Acts of the Apostles, pp. 251.252.IIO 126.1

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents