Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Ìwọ̀n-tu-wọ̀n-sì

  Gbogbo omo Olórun gbodò mo ìwúlò ìwòn-tun-wònsì nínú jíje, wíwò àti isé-sísé kí ó lè se isé tí ó dára jùlo fún Olórun. Nígbà tí òsìsé bá ń pòruurù nítorí isé àti ìtójú, tí ó sì sisé kojá àyè nínú okàn àti ara rè, kí ó yèbá láti sinmi fún ìgbà díè, kì se fún ìgbéga ìsé ara rè bíkòse kí ó lè múra fún isé tí ó ń be ní iwájú. A ní òtá tí kìí sinmi, tí ó ń wá gbogbo ònà tí a le fi kùnà láì mú ìdánwò rè borí wa. Nígbà tí okàn wa bá wà ní ìpòruurù, tí ó sì re ara wa, yóò fi ìdí èyí gbé okàn wò pèlú ìsòro tí ó le jù, kí o lè rí ìsubú omo Olórun. Jé kí òsìsé Olórun fi ogbón tójú agbára rè, nígbà tí ó bá ti rè ẹ́ pèlú isé, kí ó yera, kí ó sinmi, kí ó sì bá Jésù sòrò.-Review and Herald, Nov. 14, 1893.IIO 247.4

  Àsìlò agbára wa má ń ké kúrú iye àkókò tí ayé wa lè wúlò fún ògo Olorun. Ó sì má mú wa wà ní ipò tí a yóò fi ye fún isé Olórun, tí ó yàn wá láti se. Tí a bá gba ará wa láàyè láti kó ìwà tí ó dára, kí a má réde òru, kí a má je oúnje tí ó léwu fún ìlera wa, a fi ìfilólè àìní-agbára lélè. Kí a má se eré ìdárayá, kí a má ṣe àṣìlò okàn àti ara a wa, à ń bá a ìfi lélè àti ètò asèdá jé nínú ara wa. Àwon tí ó gé ayé won kúrú jé kí ayé won di aláìye fún isé Olórun bí won se yapa sí òfin ìgbé ayé, wón sì jèbi olè jíjà sí Olórun. Wón ja àwò ara won lólè pèlú. Ànfààní àti ìbùkún elòmíràn, isé tí Olórun rán won láti se nínú ayé, wón ti fi owó ara won bàá jé. Wón sì tún so ara won di aláìye níwòn ìgbà kúkúrú tí won ó lò láyé. Olórun mú wa gégé bí òdaràn nígbà tí a bá fi owó ara wa nípa ìwà àìtó jé kí ayé ó má rìí rere wa gbà.- Christ’s Object Lessson, pp. 346, 347.IIO 248.1

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents