Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Ní Ìbẹ̀rẹ̀ Pẹ̀pẹ̀ Ayé e Wọn

    Jẹ ki àánú àti ọ̀yàyà ti òjíṣẹ́ fara hàn nínú ìtọ́jú níti ọmọ. Ó yẹ kí o rántí pé wọ́n jẹ́ ọmọ kékeré l’ọ́kùnrin àti l’óbìnrin, àwọn ọ̀dọ́mọde nínú ìdílé Ọlọ́run.Eléyìí lè mú wọn súnmọ́, kí ó sì mú wọn ṣ’ọ̀wọ́n sí Olúwa, tí a bá sì kọ́ wọn dáadáa tí wọ́n sì gba ìbáwí, wọn yóò ṣe iṣẹ́ fún un, pàápàá jùlọ ìgbà ọ̀dọ́.-Testimonies, vol.4, pp397, 398.IIO 31.1

    Ẹ máṣe ya àwọn ọ̀dọ́ ní pọ̀sìn, jẹ́ kí wọn nípìn- ín nínú ẹrù iṣẹ́ ìjọ.Jẹ́ kí wọn mọ̀ pé wọ́n nípa nínú ìrànlọ́wọ́ àti ìbùkún ẹlòmíràn.Pàápàá jùlọ, kí àwọn ọmọdé kọ́ láti ṣe ìránṣẹ́ ti ìfẹ́ àti àánú fún àwọn tí wọn kò ṣoríire bi i ti wọn.-Testimonies, vol.6,p.435.IIO 31.2

    Kí àwa òbí kọ́ àwọn ọmọ wa ní ìwúlò àti lílo àkókò bí ó ṣe tọ́. Kọ́ wọn láti ṣe nǹkan fún Ọlọ́run tí yóò bu ọlá fún Ọlọ́run àti tí yóò mú ìbùkún bá àwọn ènìyàn níye lórí láti jà fún.Ní pàtàkì jùlọ, ní ìbẹ̀rẹ̀ ayé e wọn, wọ́n lè jẹ́ ajíhìnrere fún Ọlọ́run.-Christ Object Lessons, p.345.IIO 31.3

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents