Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Kíkójọpọ̀ Wá Sí Ilé Ẹ̀kọ́ Ọjọ́ Ìsinmi

    Iṣẹ́ mìíràn tí gbogbo wa lè kópa wà nínú u rẹ̀ ni kíkó àwọn ọmọdé àti ọ̀dọ́ sínú ilé ẹ̀kọ́ ọjọ́ ìsinmi. Ní ọ̀nà yìí àwọn ọ̀dọ́mọdé le è ṣiṣẹ́ pẹ̀lú agbára a wọn fún Olugbala ọ̀wọ́n. Wọ́n lè mú àtúnṣe bá àyànmọ́ fún àwọn ọkàn.Wọ́n lè ṣiṣẹ́ tí ó lọ títí tí ó sì tóbi fún ìjọ àti fún aráyé èyí tí a kò le è mọ̀ rárá títí di ọjọ́ ìṣirò, nígbà tí a yóò sọ “Kú u ṣẹ́” fún ẹni rere àti olóótọ́.-Review and Herald, June 10, 1888.IIO 130.2

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents