Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Alákatakítí Àti Àgbékalẹ̀ Tí Kò Múnádóko

    Ní báyìí,èṣù ń ṣiṣẹ pẹlu gbogbo ọgbọ́n àrekérekè e rẹ̀,agbàra ìtànjẹ, láti mú kí àwọn ènìyàn kúrò níbi iṣẹ́ ìránṣẹ́ ańgẹ́lì kẹ́ta,èyí tí ó yẹ kí a tàn ká pẹ̀lú agbára ń lá. Nígbà tí ọ̀tá rí i pé Ọlọ́run bùkún àwọn ènìyàn a RẸ̀, tí ó sì ń pèsè wọn sílẹ̀ láti mọ ìyàtọ̀ àwọn ìtànjẹ̀ rẹ̀, yóò ṣiṣẹ́ pẹ̀lú agbára ti o wa níkáwọ́ ọ rẹ̀ láti mú akatakiti wà ní ọna kan àti àgbékalẹ̀ tí kò múnádóko ní ọ̀nà kejì, kí ó baà lè kóre àwọn ọkàn. Àsìkò nìyí fún wa láti ṣóra láìsinmi fún ìgbésẹ̀ àkọ́kọ́ tí èṣù lè gbé ní títẹ̀ síwájú láarin wa.-Review and Herald, Jan.24, 1893.IIO 40.1

    Àwọn oníwà àgàbàgebè wà nínú àwọn ìjọ ọ wa.Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn alágbékalẹ̀ òdì tí wọ́n lè ṣọ àṣehàn-an wọn di àìgbọdọ̀ máṣe, ṣùgbọ́n tí wọn kò lè tàn bí ìmọ́lẹ̀ nínú ayé.-Review and Herald, March 24,1891.IIO 40.2

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents