Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Fífi Ìfẹ́ Ìbánikẹ́dùn Hàn

  Àwọn tí wọ́n ń ja ogun ti ayé nígbà tí kò gún gẹ́gẹ́ ńi ó le è ri\7 ìtura àti ìfagbára fún ni nípa àwọn àkíyèsí tí kò ná wọn ní n nkànkan. Ọ̀rọ̀ àánú tí a sọ, àwọn ìfetísílẹ̀ tí a fún wọn, yóò gba àwọn ìkuukùu ti ìdánwò àti iyèméjì tí ó kójọpọ̀ sí ọkàn, Èrò ọkàn tòótọ́ tí ó ń ṣe ìbánikẹ́dùn bí i ti Kristi, tí a ṣe ni ọna ti o rọrun, ní agbára láti ṣí lẹ̀kùn àwọn ọkàn tí wọ́n nílò ìfọwọ́kàn ẹlẹgẹ́ ẹ ti Ẹ̀mí Mímọ́ ọ ti Kristi. - Testimonies, vol.9, 30.IIO 123.3

  Ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn ọkàn ni a le è dé ní ọ̀nà tí ó rọrùn, ní ọ̀nà ìrẹ̀lẹ̀. Àwọn tí ó lóye jùlọ, tí à ń wò tí a sì ń yìn ní ayé bí àwọn ọkùnrin àti obìnrin tí wọn lẹ́bùn, ni wọ́n sọjí nípa àwọn ọ̀rọ̀ tí ó rọrùn tí ó ń ṣàn jáde láti ọkàn ẹni tí ó fẹ́ Ọlọ́run, tí ó sì lè sọ níti ìfẹ́ bí ó ṣe rí àti bí ayé ṣe ń sọ nípa ohun ti ọkàn-an rẹ̀ ń ronú lé tí ó sì ń jẹ́. Ní ọ̀pọ̀ ìgbà àwọn ọ̀rọ̀ tí a pèsè sílẹ̀ dáadáa tí a sì ṣe àṣàrò lé lórí lè ní ipa díẹ̀. Ọmọ Ọlọrun lọ́kùnrin tàbí lóbìnrin tí ó sọ ọ̀rọ̀ pẹ̀lú inú kan ṣùgbọ́n ní tòótọ́, lè ṣí ilẹ̀kùn àwọn ọkàn tí wọ́n ti tìpa tipẹ́ tipẹ́.- Testimonies, vol.6, p.115.IIO 124.1

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents