Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Ìgbáradì

  Jé olótító akoni, láti fi ìyìn eni tí ó pè ó kúrò nínú òkùnkùn sínú ìmólè ń lá a Rè.-Review and Herald, Jan. 24, 1893.IIO 243.5

  Àwon òsìsé Olórun gbodò gbáradì láti yara sisé bí ìpèsè sílè ẹ Rẹ̀ bá se lànà. Ìdènà bíńtín ni ipasè won má fún Sàtánì ní ààyè láti borí won.-Patriarchs and Prophets, p. 423.IIO 244.1

  Àwon ènìyàn Rè tí ó ń pa òfin mó gbodò dúró nígbà gbogbo láti sisé.-Testimonies, Vol. 8, p. 247.IIO 244.2

  Àwon tí ó ń sojú Olórun nítòótó ń sisé fún rere àwon elòmíràn. Won yóò nínú ìmútèsíwájú isé Olórun ní ilé àti lóko. À ń rí won, béè là ń gbó won, a sì ń rí ipa won, ní ìpéjopò àdúrà. Won a máa gbìyànjú láti sojú àlùfáà. Won kìí wá ti ara won tàbi gba oríyìn fún isé rere won, sùgbón wón sisé pèlú ìrèlè àti òtító, nígbà tí wón bá sisé ń lá tàbí kékeré nítorí Kristi ti se òpòlopò fún won.-Review and Herald, Sept. 6, 1881.IIO 244.3

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents