Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Àwọn Ángẹ́lì Ń Ṣe Ìpèsè Ọ̀nà

  Mo rì i pé iṣẹ́ ẹ ti òtítọ́ ìsinsinyìí gbọdọ̀ jẹ́ èyí tí gbogbo o wa dunnú sí. Ìwé àtẹ̀jáde ti òtítọ́ náà jẹ́ iṣẹ́ tí Ọlọ́run ti yàn, bí ọ̀nà láti ṣe ìkìlọ̀, tuni nínú, bániwí, gbani níyànjú tàbí dáni lẹ́bi àti fún gbogbo ẹni tí ó ṣe àkíyèsí àìsọ̀rọ̀, tí àwọn ìránṣẹ́ tí kì í sọ̀rọ̀ lè mú wá. Àwọn ángẹ́lì Ọlọ́run ní ipa láti kó nípa pípèsè àwọn ọkàn láti yà sí mímọ́ nípa òtítọ́ tí a tẹ̀ jáde, kí wọn ba à le è wà ní ìmúrasílẹ̀ fún àwọn ìran tí ó lọ́wọ̀ níwájú u wọn.- Testimonies, vol.1, p.590.IIO 154.3

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents