Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Ìgboyà Àti Òtítọ́

    Ohun tí ìjo nílò lónìí lákókò ewu yìí ni, àwon akogun bí Páùlù, wón ti kó ara won fún ìwúlò, wón ní ìrírí tí ó jinlè nínú isé Olúwa, tí ó sì ní ìtara tí ó gbóná janjan. Àwon okùnrin tí a yà sí mímó, tí ó ní èmí ìfarajìn, tí ó ń sá fún ìdánwò àti isé, àwon tí ó ní ìgboyà àti òtító, ninu ọkan àwon tí Kristi ti pilẹ “ìrètí ògo”,ati tí iná èmí ti fowó ba enu won ni yoo “wàásù òrò naa”. Ní wíwá irú àwon ìránsé béè, ó ń rẹ isé Olórun,àsìse ń lá bíi májèlé olóro dojúko ìwà omo èdá aráyé, tí ó fi ìrèdànù bá ìrètí òpòlopò omo ènìyàn.-The Acts of Apostles, p. 507.IIO 244.4

    Nínú ìjà ogun tóle, ní àarin òtá, e wo àdánù àti ìjìyà, isé èmí gbígbàlà gbodò tèsíwájú. Nínú ìjà ogun kan, nígbà tí wón ń lu egbé àwon omo kan láti owó àwon òtá, èni tí a yàn síwájú dúró gboin bí àwon ọ̀wọ́ ogun ti padà sẹ́hìn.. Ólórí ogun ké pe eni tí a yàn láti “mú wá” sùgbón eni tí a yaǹ síwájú dáhùn pé “mú àwon omo ogun wá sí ibí éyí ni isé tí ó kan gbogbo òjísé òtító láti mú àwon ènìyàn wá sí ibi ìwò o wọn. Olórun pè wá láti wá tokàn-tokàn. Gbogbo wa ni ó mò pé èsè gbogbo àwon tí ó pe ara won ní Kristeni ni àìní ìgboyà àti agbára láti mú ara won àti àwon tí ó súnmó won dé ìdiwòn. —Testimonies for the Church 9:45, 46.IIO 244.5

    Olorun kò le lo àwon ènìyàn tí ó fòyà láti dúró gboin nínú ìgbà ewu yìí, nígbàti a nílò okun, ìgboyà àti ipá gbobgo. Ó ń pe àwon ènìyàn tí yóò ja ìjà òtító láti dojúko èbi tí yóò jà lòdì sí agbára àti ogun, tí ó dojúko àwon aláse òkùnkùn ayé yìí, àti àwon èmí búburú tí ó wà níbi gíga ayé yìí. Irú àwon béè ni Olúwa yóò wí fún pé “Kúusé omo òdò rere.-“Prophets and Kings, p. 142.IIO 245.1

    Olorun ń pe àwon eni bíi Èlíjà, Nàtáníèlì, àti Jòhánù Onítèbomi — àwon okùnrin tí ó gba isé rè pèlú òtító, láìro ohunkóhun tí ó lè dé, àwon tí yóò so òtító pèlú ìgboyà, bí ó tilè gbà láti fi gbogbo ohun tí wọ́n ní jì.-Prophets and Kings, p. 142.IIO 245.2

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents