Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Ìgbàgbó

    Àwon òsìsé Olórun nílò ìgbàgbó nínú Olúwa. Kò ní àìnífokànsì ìlàkàkà wa. Omo mi ise won. Ó yan àwon èmí òrun láti sisé pèlú àwon tí ń sisé Olórun. Nígbà tí a bá rò pé Olórun kò níi se gégébí Ó ti so, àti pé kò ní àkókò láti mójú tó àwon òsìsé Rè, a ta àbùkù sí Elédàá wa.-Southern Watchman, Aug. 2, 1904.IIO 234.1

    Àwon òsìsé Olórun nílò ìfé tí ó jinlè. A lè wá dáwa lékun ní ìrísí wa, sùgbón, ìmólè wa tàn léyìn wákàtí òkùnkùn. Okun àwon tí ó sin Olórun nínú ìgbà àti ìfé yóò di òtun ní ojó dé ojó.-Gospel Workers, p. 262.IIO 234.2

    Ìgbàsókè, dídúró sinsin nínú ìpìlè àti ìmúdúró ohun tí à ń lépa wa nínú ìgbàgbó tí ó jìnnà, tí ìgbà tàbí ìyà kò lè mú kúrò.-Christ’s Object Lesson, p. 147.IIO 234.3

    Òpòlopò ìgbà ni Krìstèénì dojúko ewu, béè isé ìsìn lè lera láti se. Èrò ìparun, ìdè tàbí ikú wà léyìn. Síbè, ohùn Olórun wípé “Tèsíwájú”. A gbodò tèlé àse yìí, bí ó tilè jé pé, ojú wa kò lè rí òkùnkùn tí ó ń be níwájú àti ìjì tí ó ń fi esè wa.IIO 234.4

    Àwon ìdènà tí ó dojúko ìtèsíwájú wa kò ní pòórá níwájú okàn tí ó ń siyèméjì. Àwon tí ó ń dúró de ìgbà tí àwon ohun tí kò yé won yóò pòórá kí won tó tèlé àse Olúwa, kì yóò tèlé àse Rè rárá. Aláìní-ìgbàgbó wípé “Jé kí a dúró de ìgbà tí a yóò mú àwon ìdènà kúrò, kí a sì rí ọ̀nà a wa dáradára”. Sùgbón ìgbàgbó ń tì wá síwájú pèlú ìgboyà, ó ń fun wa ní ìrètí àti ìgbekèlé nínú ohun gbogbo.-Patriarchs and prophets, p. 290.IIO 234.5

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents