Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    ORÍ KẸẸ̀DỌ́Ọ́GBỌ̀N Ẹ̀MÍ MÍMỌ́

    Ìlérí Náà

    Fún àwa lónìí, bí ìlérí èmí mímó ti wà fún àwon omo èyìn àkókó, Olórun yóò fi fún okùnrin àti obìnrin pèlú agbára látòkè wá, bí ó ti fi fún àwon tí ó gbó òrò ìyè ní ojó Péntíkòstì. Ní àkókò yìí, èmí rè àti ore-òfé wà fún gbogbo àwon tí ó nílò rè, tí yóò sì gbà pèlú òrò rè.-Testimonies, Vol.8, p. 20.IIO 250.1

    Ìlérí èmí-mímó kò wà fún àwon tí ó jé ojó-orí kan, tàbí ìrankan. Ó so pé èmí òhun yóò wà pèlú àwon omo èyìn títí dé òpin. Láti ojó Péntíkósti títí dé ìgbà tí a wà yìí, àti rán olùtùnú fún gbogbo àwon tí ó ti fi ara won jìn fún Olórun àti isé Olórun.-The Act of Apostle, p.40.IIO 250.2

    Lóòótọ́ ni pé ní ìgbà ìkẹyìn, nípa isé Olórun nínú ayé yìí bá tán, ipa àwon tí a yàn nípasè èmí-mímó yóò jé kí àánú àtòrun wá. Nípasè òjò tí ó tètè rò, tí ó sì tún rò nígbà ìkeyìn ní Ìlà Oòrùn nígbà ìfúnrúngbìn àti ìkórè, Wale Heberu so àsotélè ore-òfé èmí-mímó láì ní òdiwòn lórí ìjo Olórun. Òjò èmí-mímó ní ìgbà àwon àpóstélì ní ìbèrè ìròjò tí ó tètè tàbí tí ó pé rò, èmí-mímó yóò wá pèlú ìjo òtító.-The Acts of Apostles, p. 54, 55.IIO 250.3

    Òjò èmí-mímó ní ìgbà àwon aposteli jé “akọrọ ojo”, àbáyorí rẹ si jé ologo. Òjò arọkuro yìí, yóò sì rò ní àròòdá. Kíni ìlérí fún àwon tó ń gbé ní ìgbà yìí? E kojú síbi gíga, èyin tí ó wà nínú ìgbèkùn ìrètí, àti pé lónìí Mo so wípé mà fifún yín ní ìlopo méjì”. “E bèèrè òjò lówó Olórun, ní àkókò òjò àrọ̀kúrò yìí, Olórun yóò so kùrukùru di mímo, yóò sì ro òjò fún gbogbo koríko.-Testimonies, Vol. 8, p. 21.IIO 251.1

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents