Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Ẹ̀gbà a Ti Ẹ̀mí

  Agbára ń wà nípa ìdárayá. Gbogbo ẹni tí ó ṣetán láti lo agbára tí Ọlọ́run fún wọn, ni yóò ní agbára kíkún láti yà sọ́tọ̀ fún iṣẹ́ ìsìn-in RẸ̀. Àwọn tí wọn kò ṣe n ǹkan nínú iṣẹ́ Ọlọ́run, yòò bàkù láti dàgbà nínú oore-ọ̀fẹ́ àti nínú ìmọ̀ ti òtítọ́. Ọkùnrin tí yóò sùn sílẹ̀ tí ó sì kọ̀ láti fi àwọn ẹ̀yà ara a rẹ̀ ṣe ìdárayá, láìpẹ́ yóò sọ gbogbo agbára nù láti lò wọ́n. Báyì í, tí Krìístẹ́nì tí kò ní lo àwọn agbára tí Ọlọ́run fún-un kò ní bàkù nìkan láti dàgbà sókè nínú u Krístì, ṣùgbọ́n yóò pàdánù agbára tí ó ti ní tẹ́lẹ̀, yóò sì di arọ nínú ohun ẹ̀mí.IIO 106.5

  A fi àwọ́n tí, pẹ̀lú ìfẹ́ fún Ọlọ́run àti arákùnrin-in wọn bá ń làkàkà láti ran ẹlòmíràn lọ̀wọ́ ni a fìdí i wọn múlẹ̀, fún lágbára, tí wọ́n fi ìdí kalẹ̀ nínú òtítọ́. Onígbàgbọ́ tòótọ́ ń ṣiṣẹ́ fún Ọlọ́run kì í ṣe fífi agbára rọ́lù, ṣùgbọ́n nínú ìpìlẹ̀; kì í ṣe fún ọjọ́ kan tàbí osù kan, ṣùgbọ́n ní gbogbo àkókò ìgbé ayé e wọn.- Testimonies, vol.5, p.393.IIO 106.6

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents