Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Yíyan Àwọn Olórí Tí Ó Kúnjú Òṣùwọ̀n Fún Ìkọ́ni

  Ìṣọ́ra ń lá ni a gbọdọ̀ ṣe nínú u yíyan àwọn olórí fún àwọn ìjọ tì a ṣẹ̀ṣẹ̀ dá sílẹ̀. Jẹ́ kí wọn jẹ́ àwọn ọkùnrin àti àwọn obìnrin tí wọ́n yípadà dáa dáa. Jẹ́ kí a yan àwọn tí ó kúnjú òṣùwọ̀n láti fún ni ní ẹ̀kọ́, àwọn tí wọn le è jẹ́ òjíṣẹ́ nínú ọ̀rọ̀ àti ní ìṣe. Ó pọn dandan fún iṣẹ́ yì í ní gbogbo ẹ̀ka.- Testimonies,vol.6, p.85.IIO 61.5

  Àwọn alàgbà àti àwọn tí wọ́n ń darí nínú ìjọ gbọdọ̀ fi kún èrò inú Correct Sí àwọn èrò fún ṣíṣe iṣẹ́ yìí. Wọ́n gbọdọ̀ to àwọn ọ̀rọ̀ náà lẹ́sẹ̀ẹsẹ kí àwọn ọmọ ìjọ kọ̀ọ̀kan ba à lè ní ipa láti kó, kí ẹnikẹ́ni má baà darí ìgbésí ayé àìléro, ṣùgbọ́n kí gbogbo wọn le è ṣe àṣepé ohun tí wọ́n le è ṣe gẹ́gẹ́ bí onírúurú agbára wọn.... Ó ṣe pàtàkì pé irú ẹ̀kọ́ yìí gbọdọ̀ jẹ́ èyí tí ao fún àwọn ọmọ ìjọ kí wọn má ba à jẹ́ onímọ̀-tara-ẹni- nìkan, olùfọkànsìn, òṣìṣẹ́ tí ó kúnjú òṣùwọ̀n fún Ọlọ́run, áti pé nípa ọ̀nà yìí nìkan ni a fi lè dènà ìjọ láti má jẹ̀ ẹ́ aláìléso àti òkú....Jẹ́ kí olúkúlùkù ọmọ ìjọ jẹ́ akíkanjú òṣìṣẹ́,- Òkúta ààyè, ẹni tí ó ń fún ìmọ́lẹ̀ jáde nínú u tẹ́ḿpìlì Olúwa.- Review and Herald, Sept.2, 1890.IIO 62.1

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents