Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Àwọn Ìbéèrè Pàtàkì

  A gbé ayérayé ṣíwájú ù wa.A fẹ́rẹ̀ gbé aṣo ìlékè náà sókè . Kíni à ń rò nípa, tí a dìrọ̀ mọ́ ìdẹ̀rùn ìfẹ́ ìmọ-tara-ẹni-nìkan-an wa nígbà tí àyíká a wa kún fún àwọn ọkàn tó ń ṣègbé?IIO 80.1

  Ǹ jẹ́ ọkàn-an wa ti yigbì pátápátá?IIO 80.2

  Ṣé a kò rí tàbí lóye pé a níṣẹ́ láti ṣe fún àwọn ẹnìkejì i wa?IIO 80.3

  Ará lọ́kùnrin àti lóbìnrin, ṣé o wà lára àwọn tí wọ́n lójú tí wọn kò fi ríran, wọ́n létí wọn kò fi gbọ́ràn?IIO 80.4

  Ṣé lásán ni Ọlọ́run fún ọ ní ìmọ̀ ti ara à rẹ?IIO 80.5

  Ṣé láṣán ni ó ti rán ìkìlọ̀ lẹ́yin ìkìlọ̀ sí ọ pé òpin ń súnmọ́?IIO 80.6

  Ṣé o gbàgbọ́ nínú jíjẹ́wọ́ ọ̀rọ̀ ọ RẸ̀ nípa ohun tí ó ń bọ̀ wá sórí aye?IIO 80.7

  Ṣé o gbàgbọ́ pé ìdájọ́ Ọlọ́run ń rọ̀ dẹ̀dẹ̀ lórí àwọn olùgbé inú ayé?IIO 80.8

  Báwo ni ó wa ṣe le jòkó pẹ̀lú ìdẹ̀ra láìbìkítà àti láì náání?- Testimonies, vol.9, pp. 26, 27.IIO 80.9

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents