Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
 • Results
 • Related
 • Featured
No results found for: "".
 • Weighted Relevancy
 • Content Sequence
 • Relevancy
 • Earliest First
 • Latest First
  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents

  Iṣẹ́ Ìjèrè Ọkàn Nílò Àwọn Ọlọ́gbọ́n Òṣíṣẹ́

  E pèsè àwon òsìsé láti lọ sí àwon ìlú ńlá àti àròko. A nílò àwon ologbón òsìsé tí won yóò jèrè àwon okàn ní ibi gbogbo tí won yóò sì fún won ní àǹfaàní láti dàgbà. Ó jé isé àwon ènìyàn Olórun láti lọ sí àwon agbègbè tó wà lókèèrè. E jé kí á se àgbékalè àwon èto èyí tí ó fún wà ní àǹfaàní láti wo àwon agbègbè tuntun. Ẹ jẹ́ kí àwon òsìsé tí ó ní ìfarajìn fún isé ìjèrè okàn ó lọ láti tan ìmólé nítòsi àti lókèèrè.-Testimonies, Vol. 9, p. 118.IIO 183.4

  Òpòlopò àwon ènìyàn wà tí wón ńjósìn ní àwon ìjo ńlá-ńlá ní wón kàn wà láìsí ohun kàn pàtó tí wón ńse. Irú won leè se isé ní àseyorí tí á bá jẹ́ kí won ó jáde lọ sí àwon agbègbè tí ìmólè kò tíìdé. Àwon igi tí wón gbìn tí wón sì sùpò sójúkan náà kìí se dáradára àyàfi tí olùtójú ogbà náà bá ń fà wón tu tí wón sì ń tún won gbìn sí ibòmíràn, béèni eléyì yóò rí fún àwon ìjo wà ńlá-ńlá. Ọ̀pọ̀ àwon omo ìjo ní ó ńkú lọ nínú èmí fún irú isé báyì, wón ń se àìsàn béè sì ní won kò wúlò àyàfi tí a bá fà wón ju tí a sì tún won gbìn dáadáa ní won yóò ní ààyè láti dàgbà kí won sì ní agbára.-Testimonies, Vol, 8, p. 224.IIO 183.5

  Larger font
  Smaller font
  Copy
  Print
  Contents