Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Fojúsí Adé Tí ó Lóòrìn

    A kò gbọdọ̀ jẹ́ kí agara dá wa tàbi kí ọkàn-an wa dákú. Yóò jẹ́ àdánu ń lá ní ṣíṣé ẹ pàsí pààrọ̀ ògo tí ó ní ìfaradà fún ìdẹ̀ra, ìrọ̀rùn, àti ìgbádùn tàbí fún àwọn ìkẹ́bàjẹ́ ẹ ti ara. Ẹ̀bùn láti ọwọ́ Ọlọrun ń dúró de aṣẹ́gun. Kò sí ẹnìkan nínú u wa tí ó tọ́ sí; ó jẹ́ ohun tí a gbà pẹ̀lú ọpẹ́ láti ọ̀dọ̀ ọ RẸ̀. Ìyanu àti ológo ni ẹ̀bùn yìí yóò jẹ́, ṣùgbọ́n ẹ jẹ́ kí a rántí pé “ìràwọ̀ kan yàtọ̀ sí ìràwọ́ nínú ògo”. Ṣùgbọ́n bí a ṣe rọ̀ wá láti gbìyànjú fún ìṣẹ́gun, ẹ jẹ́ kí áfojúsùn-un wa wà nínú agbára ti Jesu, fún adé tí ó lóòrìn pẹ̀lú àwọn ìràwọ̀. “Àwọn tí ó mòye yóò má a tàn bí òfúrufú, àti àwọn tí wọ́n bá jèrè ọ̀pọ̀ sí òdodo bí àwọn ìràwọ̀ títí láí àti láí”.Review and Herald, Oct.25, 1881.IIO 108.4

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents