Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents

ISE ISIN ONIGBAGBO

 - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Ìpè Fún Àwọn Nehinmáyà Òde Òní.

    Ìdì pàtàki wà fún wa láti ní àwọn Nehemiah nínú ìjọ lónìí — kìí se àwọn ènìyàn tí wọn leé wàásù tàbí gbàdúrà nìkan ṣùgbọn àwọn ènìyàn tí àdúrà wọn àti ìwáàsù wọn ní ìtara fún èròǹgbà ọkàn tí ó fẹsẹ̀ múlẹ̀. Ìṣẹ́ tí àwọn ara Hébérù òlódodo wọnyí ṣe jẹ́ irú èyí tí ó yẹ kí àwọn asáájú àti àwọn oníwàásù ó mú ní ọ̀kúnkúndùn. Gbogbo ìgbà tí wọn bá ní àgbékalẹ̀ ni ò yẹ kí wọn gbée wá síwájú ìjọ fún ìfọ́wọ́sowọ́pọ̀ wọn. Ẹ jẹ̀ kí òye àgbékalẹ̀ yìí ó ye gbogbo ènìyàn kí wọn sì ṣè alábàápín rẹ̀ nìgbá nàá nì wọn yóò ní ìfẹ́ sí àṣeyọrí rẹ̀. Àṣeyọrí iṣẹ́ odi mímọ tí Nehemiah ṣe yìí fihàn wá ohun tí àdúrà, ìgbàgbọ́ iṣẹ takuntakun tó kún fún ọgbọ́n leè mú wá. Ìgbàgbọ tó wá láàyè yóò mú iṣẹ́ tẹ̀síwájú pẹ̀lú agbára. Irú ẹ̀mí tí ó wà nínú àwọn adarí ni yóò farahàn nínú àwọn ènìyàn. Tí àwọn olórí bá fi írẹ̀lẹ̀ jéwọ́ òtítọ́ pàtàkì yìí èyí tí a óó fi dán ayé wò ní àkókò yìí kò bá ní ìtara gidigidi láti pèsè ọkàn àwọn ènìyàn sílẹ̀ láti dúró ní oIIO 177.2

    ọjọ Olúwa, kó sí ohun mìíràn tí a tún ń retí ju wípé kí a ní ìjọ tí kò bìkítà, ọ̀lẹ àti ìjọ tí ó fẹ́ràn afẹ́ ayé lọ.-Southern Watchman, Mar. 29, 1904.IIO 177.3

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents